1 Kíróníkà 15:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣekaríyà, Ásíélì, Ṣémírámótì, Jẹ́híélì, Únínì, Élíábù, Máséíà àti Beniáyà àwọn tí ó gbọdọ̀ ta láétírì gẹ́gẹ́ bí àlámótì,

1 Kíróníkà 15

1 Kíróníkà 15:11-22