1 Kíróníkà 14:4-7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

4. Èyí ni orúkọ àwọn ọmọ náà tí wọ́n bí fún un níbẹ̀: Ṣámúyà, Ṣóbábù, Nátanì, Ṣólómónì,

5. Íbárì, Élíṣúà, Élífélétì,

6. Nógà, Néfégì, Jáfíà,

7. Élísámà, Bélíádà, àti Élífélétì.

1 Kíróníkà 14