1 Kíróníkà 1:43 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn wọ̀nyí ni ọba tí ó jẹ ní Édómù, kí ó tó di wí pé àwọn ọba ará Ísírẹ́lì kán jẹ:Bélà ọmọ Béórì, ẹni tí orúkọ ìlú Rẹ̀ a máa jẹ́ Díníhábà.

1 Kíróníkà 1

1 Kíróníkà 1:39-44