1 Kíróníkà 1:21-32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

21. Hádórámì, Úsálì, àti Díkílà

22. Ébálì, Ábímáélì, Ṣébà.

23. Ófírì, Háfílà, àti Jóbábù. Gbogbo àwọn wọ̀nyí sì jẹ́ àwọn ọmọ Jókítanì.

24. Ṣémù, Árífákásádì, Sẹ́bà,

25. Ébérì, Pélégì. Réù,

26. Ṣérúgì, Náhórì, Térà:

27. Àti Ábúrámù (tí ń ṣe Ábúráhámù).

28. Àwọn ọmọ Ábúráhámù:Ísáákì àti Íṣímáẹ́lì.

29. Èyí ni àwọn ọmọ náà:Nébáíótì àkọ́bí Íṣímáẹ́lì: Kédárì, Ádíbélì, Míbísámù,

30. Míṣímà, Dúmà, Másà, Hádádì, Témà,

31. Jétúrì, Náfísì, àti Kédámù. Àwọn wọ̀nyí ni ọmọ Íṣímáẹ́lì

32. Àwọn ọmọ Kétúrà, obìnrin Ábúráhámù:Símíránì, Jókíṣánì Médánì, Mídíánì Iṣíbákì àti Ṣúà.Àwọn ọmọ Jókísánì:Ṣébà àti Dédánì.

1 Kíróníkà 1