1 Kíróníkà 1:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ọmọ Kétúrà, obìnrin Ábúráhámù:Símíránì, Jókíṣánì Médánì, Mídíánì Iṣíbákì àti Ṣúà.Àwọn ọmọ Jókísánì:Ṣébà àti Dédánì.

1 Kíróníkà 1

1 Kíróníkà 1:25-40