1 Jòhánù 5:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí àwa bá sì mọ̀ pé ó ń gbọ́ tí wa, ohunkóhun tí àwa bá béèrè, àwa mọ̀ pé àwa rí ìbéèrè tí àwa ti béèrè lọ́dọ̀ rẹ̀ gbà.

1 Jòhánù 5

1 Jòhánù 5:8-16