1 Jòhánù 5:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí sì ni ìgboyà tí àwa ní níwájú rẹ̀, pé bí àwa bá béèrè ohunkóhun gẹ́gẹ́ bí ìfẹ́ rẹ̀, ó ń gbọ́ tí wa;

1 Jòhánù 5

1 Jòhánù 5:12-21