1 Jòhánù 4:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òfin yìí ni àwa sì rí gbà láti ọwọ́ rẹ̀ wá, pé ẹni tí ó bá fẹ́ràn Ọlọ́run kí ó fẹ́ràn arákùnrin rẹ̀ pẹ̀lú.

1 Jòhánù 4

1 Jòhánù 4:11-21