1 Jòhánù 4:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ẹnikẹ́ni bá wí pé, “Èmi fẹ́ràn Ọlọ́run,” tí ó sì kórìíra arákùnrin rẹ̀, èké ni: nítorí ẹni tí kò fẹ́ràn arákùnrin rẹ̀ tí ó rí, báwo ni yóò tí ṣe lè fẹ́ràn Ọlọ́run tí òun kò rí?

1 Jòhánù 4

1 Jòhánù 4:16-21