1 Jòhánù 3:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú ohunkóhun tí ọkàn wa bá ń dá wa lẹ́bi; nítorí pé Ọlọ́run tóbi ju ọkàn wa lọ, ó sì mọ ohun gbogbo.

1 Jòhánù 3

1 Jòhánù 3:19-24