1 Jòhánù 3:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti nípa èyí ni àwa ó mọ̀ pé àwa jẹ́ ti òtítọ́, àti pé àwa ó sì dá ara wa lójú níwájú rẹ̀.

1 Jòhánù 3

1 Jòhánù 3:18-24