Sek 9:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Tire si mọ odi lile fun ara rẹ̀, o si ko fàdakà jọ bi ekuru, ati wurà daradara bi ẹrẹ̀ ita.

Sek 9

Sek 9:1-9