Sek 8:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitõtọ ọ̀pọlọpọ enia, ati awọn alagbara orilẹ-ède yio wá lati wá Oluwa awọn ọmọ-ogun ni Jerusalemu; ati lati gbadura niwaju Oluwa.

Sek 8

Sek 8:15-23