Sek 6:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ade wọnni yio si wà fun Helemu, ati fun Tobijah, ati fun Jedaiah, ati fun Heni, ọmọ Sefaniah, fun iranti ni tempili Oluwa.

Sek 6

Sek 6:13-15