Sek 1:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mo si sọ fun angeli ti o ba mi sọ̀rọ pe, Kini wọnyi? O si da mi lohùn pe, Awọn wọnyi ni iwo ti o ti tú Juda, Israeli, ati Jerusalemu ka.

Sek 1

Sek 1:13-21