Rom 3:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. NJẸ anfani ki ha ni ti Ju? tabi kini ère ilà kíkọ?

2. Pipọ lọna gbogbo; ekini, nitoripe awọn li a fi ọ̀rọ Ọlọrun le lọwọ.

Rom 3