Rom 2:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn gẹgẹ bi lile ati aironupiwada ọkàn rẹ, ni iwọ nfi ibinu ṣura fun ara rẹ de ọjọ ibinu ati ti ifihàn idajọ ododo Ọlọrun:

Rom 2

Rom 2:1-11