Rom 14:15-17 Yorùbá Bibeli (YCE)

15. Ṣugbọn bi inu arakunrin rẹ ba bajẹ nitori onjẹ rẹ, njẹ iwọ kò rìn ninu ifẹ mọ́. Ẹniti Kristi kú fun, máṣe fi onjẹ rẹ pa a kúgbe.

16. Njẹ ẹ máṣe jẹ ki a mã sọ̀rọ ire nyin ni buburu.

17. Nitori ijọba Ọlọrun kì iṣe jijẹ ati mimu; bikoṣe ododo, ati alafia, ati ayọ̀ ninu Ẹmí Mimọ́.

Rom 14