Owe 29:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Paṣan ati ibawi funni li ọgbọ́n: ṣugbọn ọmọ ti a ba jọwọ rẹ̀ fun ara rẹ̀, a dojuti iya rẹ̀.

Owe 29

Owe 29:9-19