Owe 28:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. ENIA buburu sá nigbati ẹnikan kò le e: ṣugbọn olododo laiya bi kiniun.

2. Nipa irekọja ilẹ li awọn ijoye idi pupọ, ṣugbọn nipa amoye ati oni ìmọ̀ enia kan, li a mu ilẹ pẹ.

Owe 28