Owe 16:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹniti o fi oye ṣe ọ̀ran yio ri ire; ẹniti o si gbẹkẹ le Oluwa, ibukún ni fun u.

Owe 16

Owe 16:18-22