Owe 1:16-18 Yorùbá Bibeli (YCE)

16. Nitori ti ẹsẹ wọn sure si ibi, nwọn si yara lati ta ẹ̀jẹ silẹ.

17. Nitõtọ, lasan li a nà àwọn silẹ li oju ẹiyẹkẹiyẹ.

18. Awọn wọnyi si ba fun ẹ̀jẹ ara wọn; nwọn lumọ nikọkọ fun ẹmi ara wọn.

Owe 1