Oni 12:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọ̀rọ ọlọgbọ́n dabi ẹgún, ati awọn olori akojọ-ọ̀rọ bi iṣó ti a kàn, ti a nfi fun ni lati ọwọ oluṣọ-agutan kan wá.

Oni 12

Oni 12:7-14