Oni 10:6-8 Yorùbá Bibeli (YCE)

6. A gbe aṣiwère sipò ọlá, awọn ọlọrọ̀ si joko nipò ẹhin.

7. Mo ri awọn ọmọ-ọdọ lori ẹṣin, ati awọn ọmọ-alade nrìn bi ọmọ-ọdọ ni ilẹ.

8. Ẹniti o wà iho ni yio bọ́ sinu rẹ̀; ati ẹniti o si njá ọgbà tútù, ejo yio si bù u ṣán.

Oni 10