O. Sol 7:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mo ni, emi o gùn ọ̀pẹ lọ, emi o di ẹka rẹ̀ mu: pẹlupẹlu nisisiyi ọmú rẹ pẹlu yio dabi ṣiri àjara, ati õrùn imú rẹ bi eso appili;

O. Sol 7

O. Sol 7:1-13