O. Sol 7:5-7 Yorùbá Bibeli (YCE)

5. Ori rẹ dabi Karmeli lara rẹ, ati irun ori rẹ bi purpili; a fi aidì irun rẹ di ọba mu.

6. O ti li ẹwà to, o si ti dara to, iwọ olufẹ mi ninu adùn ifẹ!

7. Iduro rẹ yi dabi igi ọ̀pẹ ati ọmú rẹ bi ṣiri eso àjara.

O. Sol 7