O. Daf 92:4-6 Yorùbá Bibeli (YCE)

4. Nitori iwọ, Oluwa, li o ti mu mi yọ̀ nipa iṣẹ rẹ: emi o ma kọrin iyìn nitori iṣẹ ọwọ rẹ.

5. Oluwa, iṣẹ rẹ ti tobi to! ìro-inu rẹ jinlẹ gidigidi.

6. Ope enia kò mọ̀; bẹ̃li oye eyi kò ye aṣiwere enia.

O. Daf 92