O. Daf 89:24-27 Yorùbá Bibeli (YCE)

24. Ṣugbọn otitọ mi ati ãnu mi yio wà pẹlu rẹ̀; ati li orukọ mi li a o gbé iwo rẹ̀ soke.

25. Emi o gbé ọwọ rẹ̀ le okun, ati ọwọ ọtún rẹ̀ le odò nla nì.

26. On o kigbe pè mi pe, Iwọ ni baba mi, Ọlọrun mi, ati apata igbala mi.

27. Emi o si ṣe e li akọbi, Ẹni-giga jù awọn ọba aiye lọ.

O. Daf 89