O. Daf 88:16-18 Yorùbá Bibeli (YCE)

16. Ifẹju ibinu rẹ kọja lara mi; ìbẹru rẹ ti ke mi kuro.

17. Nwọn wá yi mi ka li ọjọ gbogbo bi omi: nwọn yi mi kakiri tan.

18. Olufẹ ati ọrẹ ni iwọ mu jina si mi, ati awọn ojulumọ mi ninu okunkun.

O. Daf 88