O. Daf 85:11-13 Yorùbá Bibeli (YCE) Otitọ yio rú jade lati ilẹ wá: ododo yio si bojuwò ilẹ lati ọrun wá. Nitõtọ Oluwa yio funni li eyi ti o