O. Daf 84:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. AGỌ rẹ wọnni ti li ẹwà to, Oluwa awọn ọmọ-ogun!

2. Ọkàn mi nfà nitõtọ, o tilẹ pe ongbẹ fun agbala Oluwa: aiya mi ati ara mi nkigbe si Ọlọrun alãye.

O. Daf 84