O. Daf 81:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. KỌRIN soke si Ọlọrun, ipa wa: ẹ ho iho ayọ̀ si Ọlọrun Jakobu.

2. Ẹ mu orin mimọ́, ki ẹ si mu ìlu wa, duru didùn pẹlu ohun-elo orin mimọ́.

3. Ẹ fun ipè li oṣù titún, ni ìgbà ti a lana silẹ, li ọjọ ajọ wa ti o ni ironu.

O. Daf 81