O. Daf 72:18-20 Yorùbá Bibeli (YCE)

18. Olubukún li Oluwa Ọlọrun, Ọlọrun Israeli, ẹnikanṣoṣo ti nṣe ohun iyanu.

19. Olubukún li orukọ rẹ̀ ti o li ogo titi lai: ki gbogbo aiye ki o si kún fun ogo rẹ̀; Amin Amin.

20. Adura Dafidi ọmọ Jesse pari.

O. Daf 72