O. Daf 72:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE) ỌLỌRUN, fi idajọ rẹ fun ọba, ati ododo rẹ fun ọmọ ọba. On o ma fi ododo ṣe idajọ awọn enia rẹ