O. Daf 67:5-7 Yorùbá Bibeli (YCE)

5. Jẹ ki awọn enia ki o yìn ọ, Ọlọrun; jẹ ki gbogbo enia ki o yìn ọ.

6. Nigbana ni ilẹ yio to ma mu asunkún rẹ̀ wá; Ọlọrun, Ọlọrun wa tikararẹ̀ yio busi i fun wa.

7. Ọlọrun yio busi i fun wa; ati gbogbo opin aiye yio si ma bẹ̀ru rẹ̀.

O. Daf 67