O. Daf 65:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn pẹlu ti ngbe apa ipẹkun mbẹ̀ru nitori àmi rẹ wọnni: iwọ mu ijade owurọ ati ti aṣalẹ yọ̀.

O. Daf 65

O. Daf 65:5-13