O. Daf 65:12-13 Yorùbá Bibeli (YCE)

12. Papa-tutù aginju nkán: awọn òke kekèke fi ayọ̀ di ara wọn li àmure.

13. Agbo ẹran li a fi wọ̀ pápá-tútù na li aṣọ: afonifoji li a fi ọka bò mọlẹ: nwọn nhó fun ayọ̀, nwọn nkọrin pẹlu.

O. Daf 65