O. Daf 61:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. GBỌ́ ẹkún mi, Ọlọrun; fiye si adura mi.

2. Lati opin aiye wá li emi o kigbe pè ọ, nigbati o rẹ̀ aiya mi, fà mi lọ si apata ti o ga jù mi lọ.

3. Nitori iwọ li o ti nṣe àbo fun mi, ati ile-iṣọ agbara lọwọ ọta nì.

O. Daf 61