O. Daf 60:9-12 Yorùbá Bibeli (YCE)

9. Tani yio mu mi wá sinu ilu olodi nì? tani yio sin mi lọ si Edomu?

10. Iwọ ha kọ́, Ọlọrun, ẹniti o ṣa wa tì? ati iwọ, Ọlọrun, ti kò ba ogun wa jade lọ?

11. Fun wa ni iranlọwọ ninu ipọnju: nitori pe asan ni iranlọwọ enia.

12. Nipasẹ Ọlọrun li awa o ṣe akin: nitori on ni yio tẹ̀ awọn ọta wa mọlẹ.

O. Daf 60