O. Daf 6:8-10 Yorùbá Bibeli (YCE)

8. Ẹ lọ kuro lọdọ mi, gbogbo ẹnyin oniṣẹ ẹ̀ṣẹ; nitori ti Oluwa gbọ́ ohùn ẹkún mi.

9. Oluwa gbọ́ ẹ̀bẹ mi; Oluwa yio gbà adura mi.

10. Oju yio tì gbogbo awọn ọta mi, ara yio sì kan wọn gogo: nwọn o pada, oju yio tì wọn lojíji.

O. Daf 6