O. Daf 57:9-11 Yorùbá Bibeli (YCE)

9. Emi o ma yìn ọ, Oluwa lãrin awọn enia: emi o si ma kọrin si ọ lãrin awọn orilẹ-ède.

10. Nitoriti ãnu rẹ pọ̀ de ọrun, ati otitọ rẹ de awọsanma.

11. Gbigbega ni ọ, Ọlọrun, jù awọn ọrun lọ ati ogo rẹ jù gbogbo aiye lọ.

O. Daf 57