O. Daf 42:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn Oluwa yio paṣẹ iṣeun-ifẹ rẹ̀ nigba ọ̀san, ati li oru orin rẹ̀ yio wà pẹlu mi, ati adura mi si Ọlọrun ẹmi mi.

O. Daf 42

O. Daf 42:4-11