O. Daf 38:20-22 Yorùbá Bibeli (YCE) Awọn ti o si nfi buburu san rere li ọta mi; nitori emi ntọpa ohun ti iṣe rere. Oluwa, máṣe kọ̀ mi silẹ