O. Daf 34:20-22 Yorùbá Bibeli (YCE)

20. O pa gbogbo egungun rẹ̀ mọ́; kò si ọkan ti o ṣẹ́ ninu wọn.

21. Ibi ni yio pa enia buburu; ati awọn ti o korira olododo yio jẹbi.

22. Oluwa rà ọkàn awọn iranṣẹ rẹ̀; ọkan ninu awọn ti o gbẹkẹle e kì yio jẹbi.

O. Daf 34