O. Daf 149:7-9 Yorùbá Bibeli (YCE)

7. Lati san ẹsan lara awọn keferi, ati ijiya lara awọn enia.

8. Lati fi ẹ̀wọn dè awọn ọba wọn, ati lati fi ṣẹkẹṣẹkẹ irin dè awọn ọlọ̀tọ wọn;

9. Lati ṣe idajọ wọn, ti a ti kọwe rẹ̀, ọlá yi ni gbogbo enia mimọ́ rẹ̀ ni. Ẹ fi iyìn fun Oluwa.

O. Daf 149