O. Daf 148:9-12 Yorùbá Bibeli (YCE)

9. Ẹnyin òke nla, ati gbogbo òke kekere; igi eleso, ati gbogbo igi Kedari;

10. Ẹranko, ati gbogbo ẹran-ọ̀sin; ohun ti nrakò, ati ẹiyẹ́ ti nfò;

11. Awọn ọba aiye, ati gbogbo enia; ọmọ-alade, ati gbogbo onidajọ aiye;

12. Awọn ọdọmọkunrin ati awọn wundia, awọn arugbo enia ati awọn ọmọde;

O. Daf 148