O. Daf 147:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. Ẹ fi iyìn fun Oluwa: nitori ohun rere ni lati ma kọ orin iyìn si Ọlọrun wa: nitori ti o dùn, iyìn si yẹ.

2. Oluwa li o kọ́ Jerusalemu: on li o kó awọn ifọnkalẹ Israeli jọ.

3. O mu awọn onirora aiya lara da: o di ọgbẹ wọn:

O. Daf 147