O. Daf 142:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE) OLUWA ni mo fi ohùn mi kigbe pè; ohùn mi ni mo fi mbẹ̀bẹ mi si Oluwa. Emi tú aroye mi silẹ niwaju rẹ̀; emi