O. Daf 134:2-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

2. Ẹ gbé ọwọ nyin soke si ibi-mimọ́, ki ẹ si fi ibukún fun Oluwa.

3. Oluwa ti o da ọrun on aiye, ki o busi i fun ọ lati Sioni wá.

O. Daf 134