O. Daf 132:2-4 Yorùbá Bibeli (YCE)

2. Ẹniti o ti bura fun Oluwa, ti o si ṣe ileri ifẹ fun Alagbara Jakobu pe.

3. Nitõtọ, emi kì yio wọ̀ inu agọ ile mi lọ, bẹ̃li emi kì yio gùn ori akete mi;

4. Emi kì yio fi orun fun oju mi, tabi õgbe fun ipenpeju mi,

O. Daf 132